Linguistics & African Languages

Permanent URI for this communityhttps://repository.ui.edu.ng/handle/123456789/287

Browse

Search Results

Now showing 1 - 2 of 2
  • Thumbnail Image
    Item
    Iwulo ati Ipen Ija Lilo Awon Iwe Fagunwa fun Agbedide Ero Atumo Ede Onilana Isiro
    (2016) Odoje, C.O.
    Èrò Àtúmọ̀-Èdè jẹ́ tuntun ní Hé Afíríkà bí 6 tílé jẹ́ pé 6 tí gbi/e káàkiri ilé Èsìd, Amẹ́ríkà àti Yíròòpù. Ìwọ̀nba èrò àtúmọ̀-èdè díẹ̀ tí 6 tún wà fúnká mọ̀ ìlànà ìhun nítorí pé kìdí sí èròjà tí 6 tó láti fi ṣe àgbàkalẹ̀ onílànà ìṣírò tí àwọn onímọ̀ gbà pé kìí gba àkókò púpò bẹ́ẹ̀ sí fi kìdí kun fún kíkídà òfin. Bẹ́ẹ̀bá yìí ṣe àgbèlọwọ̀n lílo àwọn ìwé Fágúnwà gẹ́gẹ́ bí èròjà fún ṣe ìgbẹ́dèǹdè èrò àtúmọ̀-èdè onílànà ìṣírò. Ó báńpé àwọn ìwé Fágúnwà ní àmúyè tí 6 wúlò fún irú iṣẹ́ báyìí bí 6 tílé jẹ́ pé wọn kìdí pọ̀ tó bí a bá fi iye gbolóhùn inú wọn wé irú èrò bẹ́ẹ̀ míìrán lágbàáyé. A tún sákiyesi pé àwọn àsìté àti àsìtúmọ̀ náà wà nínú iṣẹ́ náà tí atunṣe gbọ́dọ̀ dé bá kí a tó ní àbájáde tí ó múnà dákò.
  • Thumbnail Image
    Item
    The Peculiar Challenges of SMT to African Languages
    (The Linguistic Association of Nigeria, 2013) Odoje, C.O.
    The challenges of Machine translation (MT) have been identified and classified but the classification did not consider the peculiarities of African languages. This paper therefore explores the challenges of MT and reclassifies them in relation with the uniqueness of African languages. The study uses the Yoruba language as a template for other African languages and identifies some of the peculiarities of African languages which include Tie fact that they are resource-scarce languages; dycritization, demarcation of discipline, and funding, amongst others. The paper recommends measures to overcome some of these challenges.