Iwulo ati Ipen Ija Lilo Awon Iwe Fagunwa fun Agbedide Ero Atumo Ede Onilana Isiro

dc.contributor.authorOdoje, C.O.
dc.date.accessioned2026-02-17T07:40:03Z
dc.date.issued2016
dc.descriptionIn: Inquiry in African Languages and Literatures 9 pp. 73-85
dc.description.abstractÈrò Àtúmọ̀-Èdè jẹ́ tuntun ní Hé Afíríkà bí 6 tílé jẹ́ pé 6 tí gbi/e káàkiri ilé Èsìd, Amẹ́ríkà àti Yíròòpù. Ìwọ̀nba èrò àtúmọ̀-èdè díẹ̀ tí 6 tún wà fúnká mọ̀ ìlànà ìhun nítorí pé kìdí sí èròjà tí 6 tó láti fi ṣe àgbàkalẹ̀ onílànà ìṣírò tí àwọn onímọ̀ gbà pé kìí gba àkókò púpò bẹ́ẹ̀ sí fi kìdí kun fún kíkídà òfin. Bẹ́ẹ̀bá yìí ṣe àgbèlọwọ̀n lílo àwọn ìwé Fágúnwà gẹ́gẹ́ bí èròjà fún ṣe ìgbẹ́dèǹdè èrò àtúmọ̀-èdè onílànà ìṣírò. Ó báńpé àwọn ìwé Fágúnwà ní àmúyè tí 6 wúlò fún irú iṣẹ́ báyìí bí 6 tílé jẹ́ pé wọn kìdí pọ̀ tó bí a bá fi iye gbolóhùn inú wọn wé irú èrò bẹ́ẹ̀ míìrán lágbàáyé. A tún sákiyesi pé àwọn àsìté àti àsìtúmọ̀ náà wà nínú iṣẹ́ náà tí atunṣe gbọ́dọ̀ dé bá kí a tó ní àbájáde tí ó múnà dákò.
dc.identifier.issn1118-2§06
dc.identifier.otherui_art_odoje_iwulo_2016
dc.identifier.urihttps://repository.ui.edu.ng/handle/123456789/12213
dc.language.isoother
dc.subjectAtumo.ede
dc.subjectYoruba
dc.subjectilana isiro
dc.subjectiwe Fagunwa
dc.titleIwulo ati Ipen Ija Lilo Awon Iwe Fagunwa fun Agbedide Ero Atumo Ede Onilana Isiro
dc.typeOther

Files

Original bundle

Now showing 1 - 1 of 1
Thumbnail Image
Name:
(11) ui_art_odoje_iwulo_2016.pdf
Size:
3.41 MB
Format:
Adobe Portable Document Format

License bundle

Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.61 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description: