Linguistics & African Languages
Permanent URI for this communityhttps://repository.ui.edu.ng/handle/123456789/287
Browse
2 results
Search Results
Item Ife-itumo-loju: Wiwa Ord-iperi Fun Arun Kokoro-Apa-Soja-Ara (KASA) ati Ebola(Library Press @ UF, 2021) Odoje, C. O.Ọ̀pọ̀ ọ̀nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún ṣíṣe àwárí tàbí ìṣèdá ọ̀rọ̀-ìpẹ̀rí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìṣàlàyé, ìhùn-prọ́-pọ̀, ìfìṣàpẹẹrẹ, ìlọ́wẹ̀, ọ̀rọ̀-àyálọ̀, ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú ni ó jẹ́ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá prọ́-ìpẹ̀rí fún àrùn Kókóró-Àpá-Sọjà-Àrà (KASA) àti Ebola. A ṣe àgbéyẹ̀wò 1572 ọ̀rọ̀ tí Yusuff, Adétúnjí àti Odòjé (2017) jẹ́ olóòtú fìlìmù, a sì fa àwọn tí wọ́n fẹ́ ìtumọ̀ wọn lójú yọ fún iṣẹ́ ìwádìí tí a ṣe. A ṣàwárí pé oríṣìíríṣìí mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni irú àwọn ọ̀rọ̀ yìí; kò sì sí ìyọnu láti ní òye ìtumọ̀ tuntun tí a wá wọ àwọn ọ̀rọ̀ náà lórí wọn. Ó tilẹ̀ mú ìtumọ̀ gbé tán bá àwọn ọ̀rọ̀ tuntun tí a lò wọ́n fún.Item Towards Machine Translation for Security Surveillance(Faculty of Arts, University of Benin., 2021) Odoje, C. O.; Nweya, G. O.Global insecurity is one of the main challenges facing the world in recent times and Nigeria is among the most affected with thousands of deaths and loss of property worth billions of naira. Studies show that countries are achieving better security through the use intelligence reports where languages play significant roles than through the use of arms and ammunitions. However, previous studies on Nigerian languages have concentrated on language description and language documentation with little attention paid to language use for security surveillance and intelligence gathering This paper, therefore, evaluates Google translate, from the perspective of the Igbo and Yoruba languages. with a view to determining its level of efficiency in translating for the purpose of security surveillance or intelligence gathering, identifying its potentials for achieving better security and the challenges facing its use. The study reveals that Google translate could be used for security surveillance if properly adapted despite the shortcomings of its output. Factors such as multilingualism, inadequate funding, insufficient language resources and poor infrastructural development are some of the challenges facing the proposal. The implication is that the Nigerian government at all levels can harness the potentials of this tool towards overcoming its security challenges if it invests more in security especially at the State and Local Government levels.
