Ife-itumo-loju: Wiwa Ord-iperi Fun Arun Kokoro-Apa-Soja-Ara (KASA) ati Ebola
No Thumbnail Available
Date
2021
Authors
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
Library Press @ UF
Abstract
Ọ̀pọ̀ ọ̀nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún ṣíṣe àwárí tàbí ìṣèdá ọ̀rọ̀-ìpẹ̀rí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìṣàlàyé, ìhùn-prọ́-pọ̀, ìfìṣàpẹẹrẹ, ìlọ́wẹ̀, ọ̀rọ̀-àyálọ̀, ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú ni ó jẹ́ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá prọ́-ìpẹ̀rí fún àrùn Kókóró-Àpá-Sọjà-Àrà (KASA) àti Ebola. A ṣe àgbéyẹ̀wò 1572 ọ̀rọ̀ tí Yusuff, Adétúnjí àti Odòjé (2017) jẹ́ olóòtú fìlìmù, a sì fa àwọn tí wọ́n fẹ́ ìtumọ̀ wọn lójú yọ fún iṣẹ́ ìwádìí tí a ṣe. A ṣàwárí pé oríṣìíríṣìí mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni irú àwọn ọ̀rọ̀ yìí; kò sì sí ìyọnu láti ní òye ìtumọ̀ tuntun tí a wá wọ àwọn ọ̀rọ̀ náà lórí wọn. Ó tilẹ̀ mú ìtumọ̀ gbé tán bá àwọn ọ̀rọ̀ tuntun tí a lò wọ́n fún.
Description
In: Yoruba Studies Review 4(1), pp. 139-146
Keywords
Kokoro-Apa-Soja-Ara (KASA), Ebola
