Ife-itumo-loju: Wiwa Ord-iperi Fun Arun Kokoro-Apa-Soja-Ara (KASA) ati Ebola

dc.contributor.authorOdoje, C. O.
dc.date.accessioned2026-02-17T08:30:04Z
dc.date.issued2021
dc.descriptionIn: Yoruba Studies Review 4(1), pp. 139-146
dc.description.abstractỌ̀pọ̀ ọ̀nà ni àwọn onímọ̀ ti dá lábàá fún ṣíṣe àwárí tàbí ìṣèdá ọ̀rọ̀-ìpẹ̀rí nínú èdè Yorùbá, lára wọn ni ìṣàlàyé, ìhùn-prọ́-pọ̀, ìfìṣàpẹẹrẹ, ìlọ́wẹ̀, ọ̀rọ̀-àyálọ̀, ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Ìfẹ́-ìtumọ̀-lójú ni ó jẹ́ ìwádìí yìí lógún nípa wíwá prọ́-ìpẹ̀rí fún àrùn Kókóró-Àpá-Sọjà-Àrà (KASA) àti Ebola. A ṣe àgbéyẹ̀wò 1572 ọ̀rọ̀ tí Yusuff, Adétúnjí àti Odòjé (2017) jẹ́ olóòtú fìlìmù, a sì fa àwọn tí wọ́n fẹ́ ìtumọ̀ wọn lójú yọ fún iṣẹ́ ìwádìí tí a ṣe. A ṣàwárí pé oríṣìíríṣìí mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni irú àwọn ọ̀rọ̀ yìí; kò sì sí ìyọnu láti ní òye ìtumọ̀ tuntun tí a wá wọ àwọn ọ̀rọ̀ náà lórí wọn. Ó tilẹ̀ mú ìtumọ̀ gbé tán bá àwọn ọ̀rọ̀ tuntun tí a lò wọ́n fún.
dc.identifier.issn2473-4713
dc.identifier.issn2578-692X
dc.identifier.otherui_art_odoje-ife-itumo-loju_2019
dc.identifier.urihttps://repository.ui.edu.ng/handle/123456789/12229
dc.language.isoother
dc.publisherLibrary Press @ UF
dc.subjectKokoro-Apa-Soja-Ara (KASA)
dc.subjectEbola
dc.titleIfe-itumo-loju: Wiwa Ord-iperi Fun Arun Kokoro-Apa-Soja-Ara (KASA) ati Ebola
dc.typeOther

Files

Original bundle

Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
(19) ui_art_odoje-ife-itumo-loju_2019.pdf
Size:
3.15 MB
Format:
Adobe Portable Document Format

License bundle

Now showing 1 - 1 of 1
No Thumbnail Available
Name:
license.txt
Size:
1.61 KB
Format:
Item-specific license agreed upon to submission
Description:

Collections