Atunpin Akojopo-Oro Adalorf Eko Ogbufo (Reclassification of Corpus Based Translation Study)
Date
2019
Authors
Journal Title
Journal ISSN
Volume Title
Publisher
Yoruba Studies Association of Nigeria
Abstract
Oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àwọn àkójọpọ̀-ọrọ ni ó wà lórí ìṣàpèjúwe àti àmúlò ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìṣọ̀ǹgbúfò. Fernandes ti ṣe àtúnpín ìpèka tí Baker (1995) ṣe ṣùgbọ́n ìṣàtúnpín rẹ̀ yọ ohun tí Ọ̀súndáre pè ní ọ̀gbúfò ẹlẹ́wà-èdè sílẹ̀. Èyí mú kí ó di dandan láti ṣe àtúnpín iṣẹ́ rẹ̀ kí a sì fi ààyè gba àwọn àtòjọ-ọrọ àwọn ọ̀hùnkòwé ilé Áfíríkà. Ohun tí a ṣe gan-an ni láti ṣe àgbéyẹ̀wò iṣẹ́ Baker àti Fernandes, a sì lò wọ́n láti ṣe àfikún àwọn èròjà ilé Áfíríkà tí a ṣọ̀nù nínú iṣẹ́ wọn. Òpin àbájáde irú ìṣàtúnpín báyìí kò kan ní jẹ́ èròjà ìpèka lásán, yóò fẹ́ àkójọ-ọrọ àdàlórí ẹ̀kọ́ ọ̀gbúfò lójú tó bẹ́ẹ̀ tí àbájáde iṣẹ́ ìwádìí báyìí yóò sì wúlò fún ìkọ́ni àti ìlànilọ́yé.
Description
In: Akangbe, C.A. (ed) Yoruba: The Journal of the Yoruba Studies Association of Nigeria 9(3), pp. 130-141
Keywords
Atunpfn, Eko Ogbufo, Akojodo-Oro
