Atunpin Akojopo-Oro Adalorf Eko Ogbufo (Reclassification of Corpus Based Translation Study)
| dc.contributor.author | Odoje, C.O. | |
| dc.date.accessioned | 2026-02-17T08:17:37Z | |
| dc.date.issued | 2019 | |
| dc.description | In: Akangbe, C.A. (ed) Yoruba: The Journal of the Yoruba Studies Association of Nigeria 9(3), pp. 130-141 | |
| dc.description.abstract | Oríṣìíríṣìí ẹ̀yà àwọn àkójọpọ̀-ọrọ ni ó wà lórí ìṣàpèjúwe àti àmúlò ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ìṣọ̀ǹgbúfò. Fernandes ti ṣe àtúnpín ìpèka tí Baker (1995) ṣe ṣùgbọ́n ìṣàtúnpín rẹ̀ yọ ohun tí Ọ̀súndáre pè ní ọ̀gbúfò ẹlẹ́wà-èdè sílẹ̀. Èyí mú kí ó di dandan láti ṣe àtúnpín iṣẹ́ rẹ̀ kí a sì fi ààyè gba àwọn àtòjọ-ọrọ àwọn ọ̀hùnkòwé ilé Áfíríkà. Ohun tí a ṣe gan-an ni láti ṣe àgbéyẹ̀wò iṣẹ́ Baker àti Fernandes, a sì lò wọ́n láti ṣe àfikún àwọn èròjà ilé Áfíríkà tí a ṣọ̀nù nínú iṣẹ́ wọn. Òpin àbájáde irú ìṣàtúnpín báyìí kò kan ní jẹ́ èròjà ìpèka lásán, yóò fẹ́ àkójọ-ọrọ àdàlórí ẹ̀kọ́ ọ̀gbúfò lójú tó bẹ́ẹ̀ tí àbájáde iṣẹ́ ìwádìí báyìí yóò sì wúlò fún ìkọ́ni àti ìlànilọ́yé. | |
| dc.identifier.issn | 1595-1324 | |
| dc.identifier.other | ui_art_odoje_atunpin_2019 | |
| dc.identifier.uri | https://repository.ui.edu.ng/handle/123456789/12224 | |
| dc.language.iso | other | |
| dc.publisher | Yoruba Studies Association of Nigeria | |
| dc.subject | Atunpfn | |
| dc.subject | Eko Ogbufo | |
| dc.subject | Akojodo-Oro | |
| dc.title | Atunpin Akojopo-Oro Adalorf Eko Ogbufo (Reclassification of Corpus Based Translation Study) | |
| dc.type | Other |
