Agbeyewo awon iwe itan aroso Fagunwa gege bi alo

Thumbnail Image

Date

2016

Journal Title

Journal ISSN

Volume Title

Publisher

Egbe Onimo-Ede Yoruba (Yoruba Studies Association of Nigeria)

Abstract

Yoruba bo won ni "Ajanaku kojaa mo ri nnkan firi, bi a ba ri erin ka kuku so pe a ri erin", oloogbe Danieli Orowole Fagunwa (1903-1963) kuro ni opije laarin ohkpwe itan arose Yoruba. itan aroso marun-un ptoptp ni Fagunwa ko: Ogboju Ode Ninu Igbo Irunmale (Ogboju) 1938, Igbo Olodumare (igbo) 1949, ireke Onibudo (ireke) 1949, irinkerindo Ninu Igbo Elegbeje (irinkerindo) 1954 ati Adiitu Olodumare (Adiitu) 1961. Yato si awon wonyi, Fagunwa tun ni awon ise miran bi irinajo: Apa Kini (OUP 1963); itan Oloyin (OUP 1964); Fagunwa, Delano, I.O. ati awon yooku, Asayan itan (Nelson 1959); Fagunwa ati Lasebikan, OJo Asotan (Heinemann 1964); ti a te jade leyin iku re. Fagunwa ati L.J Lewis ni o jo ko Taiwo ati Kehinde iwe Kiini, (OUP 1948); Taiwo ati Kehinde iwe Keji (OUP 1950); Taiwo ati Kehinde iwe Keta (OUP 1950); ati Taiwo ati Kehinde iwe Kerin (OUP 1951). Awon iwe itan aroso maraarun ti Fagunwa kg ni yoo je wa logun ninu pepa yii nibi ti a o ti fi oju alo wo awon itan inu iwe naa. Abala merin otooto ni a pin pepa yii si. Ifaara ni o siwaju, Alo Yoruba, Tiori itatare- ise, Afiwe Ise Fagunwa ati Alo, ati Iyapa Ise Fagunwa si Alo ni o tele ara won. Agbalogbabp ni a fi kadii ijiroro wa.

Description

Keywords

Citation

Collections

Endorsement

Review

Supplemented By

Referenced By